ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 50:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ọlọ́run wa yóò wá, kò sì ní dákẹ́.+

      Iná tó ń jó nǹkan run wà níwájú rẹ̀,+

      Ìjì tó lágbára sì ń jà ní gbogbo àyíká rẹ̀.+

  • Sáàmù 50:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Nígbà tí o ṣe àwọn nǹkan yìí, mi ò sọ̀rọ̀,

      Torí náà, o rò pé màá dà bíi tìẹ.

      Àmọ́ ní báyìí, màá bá ọ wí,

      Màá sì pè ọ́ lẹ́jọ́.+

  • Jeremáyà 16:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Lákọ̀ọ́kọ́ ná, màá san ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ohun tó yẹ wọ́n nítorí àṣìṣe wọn àti ẹ̀ṣẹ̀ wọn,+

      Nítorí wọ́n ti fi àwọn ère aláìlẹ́mìí* ti òrìṣà ẹ̀gbin wọn sọ ilẹ̀ mi di aláìmọ́

      Wọ́n sì ti fi àwọn ohun ìríra wọn kún inú ogún mi.’”+

  • Ìsíkíẹ́lì 11:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 “‘“Ṣùgbọ́n ní ti àwọn tí ọkàn wọn ṣì ń fà sí àwọn ohun tó ń ríni lára tó sì ń kóni nírìíra tí wọ́n ń ṣe, màá fi ìwà wọn san wọ́n lẹ́san,” ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́