Àìsáyà 59:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ó máa san wọ́n lẹ́san ohun tí wọ́n ṣe:+ Ó máa bínú sí àwọn elénìní rẹ̀, ó máa fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ jẹ àwọn ọ̀tá rẹ̀.+ Ó sì máa san ohun tó yẹ àwọn erékùṣù fún wọn.
18 Ó máa san wọ́n lẹ́san ohun tí wọ́n ṣe:+ Ó máa bínú sí àwọn elénìní rẹ̀, ó máa fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ jẹ àwọn ọ̀tá rẹ̀.+ Ó sì máa san ohun tó yẹ àwọn erékùṣù fún wọn.