Hébérù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó tún sọ pé: “Màá gbẹ́kẹ̀ lé e.”+ Àti pé: “Wò ó! Èmi àti àwọn ọmọ kéékèèké tí Jèhófà* fún mi.”+