Émọ́sì 5:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí pé ẹ̀ ń gba owó oko* lọ́wọ́ àwọn aláìní tí ẹ gbé oko fúnẸ sì ń gba ọkà lọ́wọ́ wọn bí ìṣákọ́lẹ̀,*+Ẹ kò ní máa gbé inú àwọn ilé tí ẹ fi òkúta gbígbẹ́ kọ́+Bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò ní máa mu wáìnì àwọn ọgbà àjàrà dáradára tí ẹ gbìn.+
11 Nítorí pé ẹ̀ ń gba owó oko* lọ́wọ́ àwọn aláìní tí ẹ gbé oko fúnẸ sì ń gba ọkà lọ́wọ́ wọn bí ìṣákọ́lẹ̀,*+Ẹ kò ní máa gbé inú àwọn ilé tí ẹ fi òkúta gbígbẹ́ kọ́+Bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò ní máa mu wáìnì àwọn ọgbà àjàrà dáradára tí ẹ gbìn.+