-
2 Àwọn Ọba 18:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Torí náà, Rábúṣákè sọ fún wọn pé: “Ẹ jọ̀ọ́, ẹ sọ fún Hẹsikáyà pé, ‘Ohun tí ọba ńlá, ọba Ásíríà sọ nìyí: “Kí lo gbọ́kàn lé?+
-
-
2 Àwọn Ọba 18:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Báwo wá ni ẹ ṣe lè borí gómìnà kan ṣoṣo tó kéré jù lára àwọn ìránṣẹ́ olúwa mi, nígbà tó jẹ́ pé Íjíbítì lẹ gbẹ́kẹ̀ lé pé ó máa fún yín ní àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti àwọn agẹṣin?
-