Léfítíkù 4:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kó wá fi lára ẹ̀jẹ̀ náà sára àwọn ìwo pẹpẹ+ tó wà níwájú Jèhófà, èyí tó wà nínú àgọ́ ìpàdé; kó sì da gbogbo ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ ẹbọ sísun, tó wà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.+ Léfítíkù 4:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Kó mú akọ màlúù náà lọ sí ẹ̀yìn ibùdó, kó sì sun ún, bó ṣe sun akọ màlúù àkọ́kọ́.+ Ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ fún ìjọ+ ni.
18 Kó wá fi lára ẹ̀jẹ̀ náà sára àwọn ìwo pẹpẹ+ tó wà níwájú Jèhófà, èyí tó wà nínú àgọ́ ìpàdé; kó sì da gbogbo ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ ẹbọ sísun, tó wà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.+
21 Kó mú akọ màlúù náà lọ sí ẹ̀yìn ibùdó, kó sì sun ún, bó ṣe sun akọ màlúù àkọ́kọ́.+ Ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ fún ìjọ+ ni.