Ìfihàn 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Kọ̀wé sí áńgẹ́lì ìjọ ní Laodíkíà+ pé: Àwọn ohun tí Àmín+ sọ nìyí, ẹlẹ́rìí+ olóòótọ́ tó sì ṣeé gbára lé,+ ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ohun tí Ọlọ́run dá:+
14 “Kọ̀wé sí áńgẹ́lì ìjọ ní Laodíkíà+ pé: Àwọn ohun tí Àmín+ sọ nìyí, ẹlẹ́rìí+ olóòótọ́ tó sì ṣeé gbára lé,+ ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ohun tí Ọlọ́run dá:+