-
Ọbadáyà 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Ilé Jékọ́bù yóò di iná,
Ilé Jósẹ́fù yóò di ọwọ́ iná,
Ilé Ísọ̀ yóò sì dà bí àgékù pòròpórò;
Wọn yóò ti iná bọ̀ wọ́n, wọn yóò sì run wọ́n,
Ẹnikẹ́ni kì yóò sì là á já ní ilé Ísọ̀,+
Torí Jèhófà fúnra rẹ̀ ti sọ ọ́.
-