Jeremáyà 50:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹ mú afúnrúgbìn kúrò ní Bábílónì Àti ẹni tó ń lo dòjé ní ìgbà ìkórè.+ Nítorí idà tó ń hanni léèmọ̀, kálukú á pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn rẹ̀,Kálukú á sì sá lọ sí ilẹ̀ rẹ̀.+
16 Ẹ mú afúnrúgbìn kúrò ní Bábílónì Àti ẹni tó ń lo dòjé ní ìgbà ìkórè.+ Nítorí idà tó ń hanni léèmọ̀, kálukú á pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn rẹ̀,Kálukú á sì sá lọ sí ilẹ̀ rẹ̀.+