ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 51:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Kí tafàtafà má lè tẹ* ọrun rẹ̀.

      Kí ẹnikẹ́ni tó wọ ẹ̀wù irin má sì lè nàró.

      Ẹ má ṣàánú àwọn ọ̀dọ́kùnrin rẹ̀.+

      Ẹ pa gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ run pátápátá.

       4 Wọ́n á ṣubú, wọ́n á sì kú ní ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà,

      A ó sì gún wọn ní àgúnyọ ní àwọn ojú ọ̀nà rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́