Sáàmù 137:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ìwọ ọmọbìnrin Bábílónì, tí kò ní pẹ́ di ahoro,+Aláyọ̀ ni ẹni tó máa san ọ́ lẹ́sanLórí ohun tí o ṣe sí wa.+ 9 Aláyọ̀ ni ẹni tó máa gba àwọn ọmọ rẹ lọ́wọ́ rẹ,Tí á sì là wọ́n mọ́ àpáta.+
8 Ìwọ ọmọbìnrin Bábílónì, tí kò ní pẹ́ di ahoro,+Aláyọ̀ ni ẹni tó máa san ọ́ lẹ́sanLórí ohun tí o ṣe sí wa.+ 9 Aláyọ̀ ni ẹni tó máa gba àwọn ọmọ rẹ lọ́wọ́ rẹ,Tí á sì là wọ́n mọ́ àpáta.+