ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 47:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 47 Sọ̀ kalẹ̀ wá jókòó sínú iyẹ̀pẹ̀,

      Ìwọ wúńdíá ọmọbìnrin Bábílónì.+

      Jókòó sílẹ̀ níbi tí kò sí ìtẹ́,+

      Ìwọ ọmọbìnrin àwọn ará Kálídíà,

      Torí àwọn èèyàn ò tún ní pè ọ́ ní ẹlẹgẹ́ àti àkẹ́jù mọ́.

  • Jeremáyà 25:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 “‘Ṣùgbọ́n tí àádọ́rin (70) ọdún bá pé,+ màá pe ọba Bábílónì àti orílẹ̀-èdè yẹn wá jíhìn* nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,’+ ni Jèhófà wí, ‘màá sì sọ ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà di ahoro títí láé.+

  • Jeremáyà 50:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 “Ẹ sọ ọ́ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè kí ẹ sì kéde rẹ̀.

      Ẹ gbé àmì kan dúró,* ẹ sì kéde rẹ̀.

      Ẹ má fi nǹkan kan pa mọ́!

      Ẹ sọ pé, ‘Wọ́n ti gba Bábílónì.+

      Ìtìjú ti bá Bélì.+

      Méródákì wà nínú ìbẹ̀rù.

      Ìtìjú ti bá àwọn ère rẹ̀.

      Àwọn òrìṣà ẹ̀gbin rẹ̀* wà nínú ìbẹ̀rù.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́