ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 47:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 47 Sọ̀ kalẹ̀ wá jókòó sínú iyẹ̀pẹ̀,

      Ìwọ wúńdíá ọmọbìnrin Bábílónì.+

      Jókòó sílẹ̀ níbi tí kò sí ìtẹ́,+

      Ìwọ ọmọbìnrin àwọn ará Kálídíà,

      Torí àwọn èèyàn ò tún ní pè ọ́ ní ẹlẹgẹ́ àti àkẹ́jù mọ́.

  • Jeremáyà 51:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 51 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

      “Wò ó, màá ru ẹ̀fúùfù tó ń pani run sókè

      Sí Bábílónì+ àti sí àwọn tó ń gbé ní Lẹbu-kámáì.*

  • Dáníẹ́lì 5:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 “Ohun tí àwọn ọ̀rọ̀ náà túmọ̀ sí nìyí: MÉNÈ, Ọlọ́run ti ka iye ọjọ́ ìjọba rẹ, ó sì ti fòpin sí i.+

  • Dáníẹ́lì 5:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Òru ọjọ́ yẹn gan-an ni wọ́n pa Bẹliṣásárì, ọba àwọn ará Kálídíà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́