ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Nígbà tí oṣù keje+ pé, tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ti wà nínú àwọn ìlú wọn, wọ́n kóra jọ sí Jerúsálẹ́mù pẹ̀lú èrò tó ṣọ̀kan.

  • Ẹ́sírà 9:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Àmọ́ ní báyìí, ìwọ Jèhófà Ọlọ́run wa ti ṣojú rere sí wa fún ìgbà díẹ̀, o ti jẹ́ kí àwọn tó ṣẹ́ kù sá àsálà, o sì ti fún wa ní ibi ààbò* nínú ibi mímọ́ rẹ,+ láti mú kí ojú wa máa dán àti láti gbé wa dìde díẹ̀ nínú ipò ẹrú tí a wà, ìwọ Ọlọ́run wa.

  • Jeremáyà 30:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Ní tìrẹ, ìwọ Jékọ́bù ìránṣẹ́ mi, má fòyà,” ni Jèhófà wí,

      “Má sì jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, ìwọ Ísírẹ́lì.+

      Nítorí màá gbà ọ́ láti ibi tó jìnnà réré

      Àti àwọn ọmọ rẹ láti oko ẹrú tí wọ́n wà.+

      Jékọ́bù á pa dà, ara rẹ̀ á balẹ̀, kò ní rí ìyọlẹ́nu,

      Ẹnì kankan ò sì ní dẹ́rù bà wọ́n.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́