Jeremáyà 51:62 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 62 Kí o sì sọ pé, ‘Jèhófà, o ti sọ nípa ibí yìí pé wọ́n á pa á run, ohunkóhun kò sì ní gbé inú rẹ̀, ì báà jẹ́ èèyàn tàbí ẹranko àti pé á di ahoro títí láé.’+
62 Kí o sì sọ pé, ‘Jèhófà, o ti sọ nípa ibí yìí pé wọ́n á pa á run, ohunkóhun kò sì ní gbé inú rẹ̀, ì báà jẹ́ èèyàn tàbí ẹranko àti pé á di ahoro títí láé.’+