-
Jeremáyà 9:25, 26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Jèhófà sọ pé, “Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀ tí màá mú kí gbogbo àwọn tó kọlà* àmọ́ tí wọn ò kọlà* lóòótọ́ jíhìn+ 26 àti Íjíbítì àti + Júdà+ àti Édómù+ àti àwọn ọmọ Ámónì+ àti Móábù+ pẹ̀lú gbogbo àwọn tí wọ́n gé irun wọn mọ́lẹ̀ ní ẹ̀bátí, tí wọ́n ń gbé ní aginjù.+ Nítorí gbogbo orílẹ̀-èdè jẹ́ aláìkọlà,* gbogbo ilé Ísírẹ́lì sì jẹ́ aláìkọlà* ọkàn.”+
-