Jeremáyà 48:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Sí Móábù,+ ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, sọ nìyí: “Nébò gbé! + nítorí wọ́n ti pa á run. Ìtìjú ti bá Kiriátáímù,+ wọ́n sì ti gbà á. Ìtìjú ti bá ibi ààbò,* wọ́n sì ti wó o lulẹ̀.+
48 Sí Móábù,+ ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, sọ nìyí: “Nébò gbé! + nítorí wọ́n ti pa á run. Ìtìjú ti bá Kiriátáímù,+ wọ́n sì ti gbà á. Ìtìjú ti bá ibi ààbò,* wọ́n sì ti wó o lulẹ̀.+