Jẹ́nẹ́sísì 19:36, 37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Àwọn ọmọbìnrin Lọ́ọ̀tì méjèèjì lóyún nípasẹ̀ bàbá wọn. 37 Èyí àkọ́bí bí ọmọkùnrin kan, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Móábù.+ Òun ló wá di bàbá àwọn ọmọ Móábù.+ Àìsáyà 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Móábù:+ Torí a ti pa á run ní òru kan,A ti pa Árì+ ti Móábù lẹ́nu mọ́. Torí a ti pa á run ní òru kan,A ti pa Kírì+ ti Móábù lẹ́nu mọ́.
36 Àwọn ọmọbìnrin Lọ́ọ̀tì méjèèjì lóyún nípasẹ̀ bàbá wọn. 37 Èyí àkọ́bí bí ọmọkùnrin kan, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Móábù.+ Òun ló wá di bàbá àwọn ọmọ Móábù.+
15 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Móábù:+ Torí a ti pa á run ní òru kan,A ti pa Árì+ ti Móábù lẹ́nu mọ́. Torí a ti pa á run ní òru kan,A ti pa Kírì+ ti Móábù lẹ́nu mọ́.