2 Kíróníkà 29:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ni Hẹsikáyà+ nígbà tó jọba, ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n (29) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Ábíjà ọmọ Sekaráyà.+ 2 Ó ń ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Jèhófà,+ bí Dáfídì baba ńlá rẹ̀ ti ṣe.+ 2 Kíróníkà 32:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ Ọba Hẹsikáyà àti wòlíì Àìsáyà+ ọmọ Émọ́ọ̀sì kò dákẹ́ àdúrà lórí ọ̀rọ̀ yìí, wọ́n sì ń ké pe Ọlọ́run lókè ọ̀run pé kó ran àwọn lọ́wọ́.+
29 Ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ni Hẹsikáyà+ nígbà tó jọba, ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n (29) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Ábíjà ọmọ Sekaráyà.+ 2 Ó ń ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Jèhófà,+ bí Dáfídì baba ńlá rẹ̀ ti ṣe.+
20 Àmọ́ Ọba Hẹsikáyà àti wòlíì Àìsáyà+ ọmọ Émọ́ọ̀sì kò dákẹ́ àdúrà lórí ọ̀rọ̀ yìí, wọ́n sì ń ké pe Ọlọ́run lókè ọ̀run pé kó ran àwọn lọ́wọ́.+