-
Diutarónómì 24:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 “Tí o bá lu igi ólífì rẹ, o ò gbọ́dọ̀ ṣe bẹ́ẹ̀ sí àwọn ẹ̀ka rẹ̀. Kí o fi ohun tó bá ṣẹ́ kù sílẹ̀ fún àjèjì, ọmọ aláìníbaba àti opó.+
-