ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 9:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Yìnyín náà bọ́ lu gbogbo ohun tó wà nínú oko ní gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì, látorí èèyàn dórí ẹranko, ó run gbogbo ewéko, ó sì run gbogbo igi oko.+

  • Ẹ́kísódù 9:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Ọ̀gbọ̀ àti ọkà bálì ti run, torí pé ọkà bálì wà nínú ṣírí, ọ̀gbọ̀ sì ti yọ òdòdó.

  • Òwe 7:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Mo ti tẹ́ àwọn aṣọ tó dára lé ibùsùn mi,

      Aṣọ ọ̀gbọ̀* aláràbarà láti Íjíbítì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́