ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 43:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Torí náà, Jóhánánì ọmọ Káréà àti gbogbo olórí àwọn ọmọ ogun pẹ̀lú gbogbo àwọn èèyàn náà kò ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà pé kí wọ́n dúró sí ilẹ̀ Júdà.

  • Jeremáyà 43:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Wọ́n wọ ilẹ̀ Íjíbítì, nítorí wọn kò ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà, wọ́n sì lọ títí dé Tápánẹ́sì.+

  • Jeremáyà 44:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 44 Ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà gbọ́ nípa gbogbo Júù tó ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ìyẹn àwọn tó ń gbé ní Mígídólì,+ ní Tápánẹ́sì,+ ní Nófì*+ àti ní ilẹ̀ Pátírọ́sì,+ pé:

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́