Dáníẹ́lì 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní ti Ọba Bẹliṣásárì,+ ó se àsè ńlá kan fún ẹgbẹ̀rún (1,000) àwọn èèyàn rẹ̀ pàtàkì, ó sì ń mu wáìnì níwájú wọn.+
5 Ní ti Ọba Bẹliṣásárì,+ ó se àsè ńlá kan fún ẹgbẹ̀rún (1,000) àwọn èèyàn rẹ̀ pàtàkì, ó sì ń mu wáìnì níwájú wọn.+