Àìsáyà 21:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ tẹ́ tábìlì, kí ẹ sì to àwọn ìjókòó! Ẹ jẹ, kí ẹ sì mu!+ Ẹ dìde, ẹ̀yin ìjòyè, ẹ fi òróró yan* apata! Jeremáyà 51:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 “Nígbà tí ọ̀fun wọn bá ń dá tòló, màá se àsè fún wọn, màá sì rọ wọ́n yó,Kí wọ́n lè yọ̀;+Nígbà náà, wọ́n á sùn títí lọ,Tí wọn kò ní jí,”+ ni Jèhófà wí.
5 Ẹ tẹ́ tábìlì, kí ẹ sì to àwọn ìjókòó! Ẹ jẹ, kí ẹ sì mu!+ Ẹ dìde, ẹ̀yin ìjòyè, ẹ fi òróró yan* apata!
39 “Nígbà tí ọ̀fun wọn bá ń dá tòló, màá se àsè fún wọn, màá sì rọ wọ́n yó,Kí wọ́n lè yọ̀;+Nígbà náà, wọ́n á sùn títí lọ,Tí wọn kò ní jí,”+ ni Jèhófà wí.