Jẹ́nẹ́sísì 10:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Kénáánì bí Sídónì+ àkọ́bí rẹ̀ àti Hétì+ Ìsíkíẹ́lì 27:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn tó ń gbé Sídónì àti Áfádì+ ló ń bá ọ tukọ̀. Ìwọ Tírè, àwọn èèyàn rẹ tó já fáfá ló ń bá ọ tukọ̀.+
8 Àwọn tó ń gbé Sídónì àti Áfádì+ ló ń bá ọ tukọ̀. Ìwọ Tírè, àwọn èèyàn rẹ tó já fáfá ló ń bá ọ tukọ̀.+