Ìsíkíẹ́lì 27:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Gbogbo àwọn tó ń gbé ní àwọn erékùṣù yóò wò ọ́ tìyanutìyanu,+Ìbẹ̀rù yóò mú kí jìnnìjìnnì bá àwọn ọba wọn,+ ìdààmú yóò sì hàn lójú wọn. Ìsíkíẹ́lì 28:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Gbogbo àwọn tó mọ̀ ọ́ láàárín àwọn èèyàn yóò wò ọ́ tìyanutìyanu.+ Ìparun rẹ yóò dé lójijì, yóò sì burú jáì,O ò sì ní sí mọ́ títí láé.”’”+
35 Gbogbo àwọn tó ń gbé ní àwọn erékùṣù yóò wò ọ́ tìyanutìyanu,+Ìbẹ̀rù yóò mú kí jìnnìjìnnì bá àwọn ọba wọn,+ ìdààmú yóò sì hàn lójú wọn.
19 Gbogbo àwọn tó mọ̀ ọ́ láàárín àwọn èèyàn yóò wò ọ́ tìyanutìyanu.+ Ìparun rẹ yóò dé lójijì, yóò sì burú jáì,O ò sì ní sí mọ́ títí láé.”’”+