-
Jeremáyà 25:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 “Nítorí náà, ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘“Nítorí pé ẹ kò gbọ́rọ̀ sí mi lẹ́nu,
-
-
Jeremáyà 27:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ní báyìí, mo ti fi gbogbo ilẹ̀ yìí lé ọwọ́ ìránṣẹ́ mi, Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì, kódà mo ti fún un ní àwọn ẹran inú igbó kí wọ́n lè máa sìn ín.
-