-
Jeremáyà 49:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
49 Sí àwọn ọmọ Ámónì,+ ohun tí Jèhófà sọ nìyí:
“Ṣé Ísírẹ́lì kò ní ọmọ ni?
Ṣé kò ní ẹni tó máa jogún rẹ̀ ni?
Kí ló dé tí Málíkámù+ fi gba Gádì?+
Tí àwọn èèyàn rẹ̀ sì ń gbé inú àwọn ìlú Ísírẹ́lì?”
2 “‘Nítorí náà, wò ó! ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà wí,
Ó máa di àwókù,
Wọ́n á sì dáná sun àwọn àrọko* rẹ̀.’
‘Ísírẹ́lì á sì sọ àwọn tó gba tọwọ́ rẹ̀ di ohun ìní,’+ ni Jèhófà wí.
-