Sáàmù 46:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Ọlọ́run ni ibi ààbò wa àti okun wa,+Ìrànlọ́wọ́ tó wà lárọ̀ọ́wọ́tó ní àkókò wàhálà.+ Náhúmù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà jẹ́ ẹni rere,+ odi agbára ní ọjọ́ wàhálà.+ Ó sì mọ* àwọn tó ń wá ibi ààbò lọ́dọ̀ rẹ̀.+ Sefanáyà 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Màá jẹ́ kí àwọn onírẹ̀lẹ̀ àti àwọn aláìní wà ní àárín rẹ,+Wọ́n á sì fi orúkọ Jèhófà ṣe ibi ààbò.