Àìsáyà 60:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn ẹnubodè rẹ máa wà ní ṣíṣí nígbà gbogbo;+Wọn ò ní tì wọ́n ní ọ̀sán tàbí ní òru,Láti mú ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè wá sọ́dọ̀ rẹ,Àwọn ọba wọn sì máa ṣáájú.+
11 Àwọn ẹnubodè rẹ máa wà ní ṣíṣí nígbà gbogbo;+Wọn ò ní tì wọ́n ní ọ̀sán tàbí ní òru,Láti mú ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè wá sọ́dọ̀ rẹ,Àwọn ọba wọn sì máa ṣáájú.+