ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 32:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  28 Torí orílẹ̀-èdè tí kò ní làákàyè* ni wọ́n,

      Kò sí ẹni tó ní òye láàárín wọn.+

  • Àìsáyà 1:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Akọ màlúù mọ ẹni tó ra òun dunjú,

      Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sì mọ ibùjẹ ẹran olówó rẹ̀;

      Àmọ́ Ísírẹ́lì ò mọ̀ mí,*+

      Àwọn èèyàn mi ò fi òye hùwà.”

  • Jeremáyà 4:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 “Nítorí àwọn èèyàn mi gọ̀;+

      Wọn ò kà mí sí.

      Ọmọ tí kò gbọ́n ni wọ́n, wọn ò sì lóye.

      Ọ̀jáfáfá* ni wọ́n nínú ìwà ibi,

      Àmọ́, wọn ò mọ bí a ti ń ṣe rere.”

  • Hósíà 4:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 A ó pa àwọn èèyàn mi lẹ́nu mọ́,* torí pé wọn kò ní ìmọ̀.

      Nítorí pé wọ́n ti kọ̀ láti mọ̀ mí,+

      Èmi náà á kọ̀ wọ́n pé kí wọ́n má ṣe àlùfáà mi mọ́;

      Àti nítorí pé wọ́n gbàgbé òfin* Ọlọ́run wọn,+

      Èmi náà á gbàgbé àwọn ọmọ wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́