ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 16:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àmọ́, inú bí Ásà sí aríran náà, ó sì fi í sẹ́wọ̀n,* torí ohun tó sọ mú kí Ásà gbaná jẹ. Ní àkókò yẹn kan náà, Ásà bẹ̀rẹ̀ sí í fìyà jẹ àwọn kan lára àwọn èèyàn náà.

  • 2 Kíróníkà 18:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ni ọba Ísírẹ́lì bá sọ fún Jèhóṣáfátì pé: “Ọkùnrin kan ṣì wà+ tí a lè ní kó bá wa wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà; ṣùgbọ́n mo kórìíra rẹ̀, nítorí kò sọ àsọtẹ́lẹ̀ rere nípa mi rí, àfi ibi ṣáá.+ Mikáyà ni orúkọ rẹ̀, ọmọ Ímílà ni.” Síbẹ̀, Jèhóṣáfátì sọ pé: “Kí ọba má sọ bẹ́ẹ̀.”

  • Jeremáyà 11:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Nítorí náà, èyí ni ohun tí Jèhófà sọ sí àwọn èèyàn Ánátótì+ tí wọ́n fẹ́ gba ẹ̀mí rẹ,* tí wọ́n sì sọ pé: “O ò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀ ní orúkọ Jèhófà,+ àìjẹ́ bẹ́ẹ̀ a ó fi ọwọ́ ara wa pa ọ́.”

  • Jeremáyà 26:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Àwọn àlùfáà àti àwọn wòlíì sì sọ fún àwọn ìjòyè àti gbogbo àwọn èèyàn náà pé: “Ikú tọ́ sí ọkùnrin yìí,+ nítorí ó sọ tẹ́lẹ̀ nípa ìlú yìí, gẹ́gẹ́ bí ẹ ti fi etí ara yín gbọ́ ọ.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́