Àìsáyà 30:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ́n ń sọ fún àwọn aríran pé, ‘Ẹ má ṣe ríran,’ Àti fún àwọn olùríran pé, ‘Ẹ má sọ àwọn ìran tó jẹ́ òótọ́ fún wa.+ Ọ̀rọ̀ dídùn* ni kí ẹ bá wa sọ; ìran ẹ̀tàn ni kí ẹ máa rí.+ Émọ́sì 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 ‘Àmọ́, ẹ̀ ń fún Násírì ní wáìnì mu,+Ẹ sì ń pàṣẹ fún àwọn wòlíì pé: “Ẹ kò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀.”+ Émọ́sì 7:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí náà, gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà: ‘Ìwọ ń sọ pé, “Ìwọ kò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀ lòdì sí Ísírẹ́lì,+ ìwọ kò sì gbọ́dọ̀ kéde ìkìlọ̀+ fún ilé Ísákì.”
10 Wọ́n ń sọ fún àwọn aríran pé, ‘Ẹ má ṣe ríran,’ Àti fún àwọn olùríran pé, ‘Ẹ má sọ àwọn ìran tó jẹ́ òótọ́ fún wa.+ Ọ̀rọ̀ dídùn* ni kí ẹ bá wa sọ; ìran ẹ̀tàn ni kí ẹ máa rí.+
16 Torí náà, gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà: ‘Ìwọ ń sọ pé, “Ìwọ kò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀ lòdì sí Ísírẹ́lì,+ ìwọ kò sì gbọ́dọ̀ kéde ìkìlọ̀+ fún ilé Ísákì.”