Émọ́sì 7:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ṣùgbọ́n ìwọ kò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀ ní Bẹ́tẹ́lì mọ́,+ nítorí pé ibùjọsìn ọba ni,+ ilé ìjọba sì ni.” Émọ́sì 7:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí náà, gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà: ‘Ìwọ ń sọ pé, “Ìwọ kò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀ lòdì sí Ísírẹ́lì,+ ìwọ kò sì gbọ́dọ̀ kéde ìkìlọ̀+ fún ilé Ísákì.”
16 Torí náà, gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà: ‘Ìwọ ń sọ pé, “Ìwọ kò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀ lòdì sí Ísírẹ́lì,+ ìwọ kò sì gbọ́dọ̀ kéde ìkìlọ̀+ fún ilé Ísákì.”