Sáàmù 99:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọba alágbára ńlá tó nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo ni.+ O ti fìdí ohun tí ó tọ́ múlẹ̀ ṣinṣin. O ti mú kí ìdájọ́ òdodo+ àti òtítọ́ wà ní Jékọ́bù. Jeremáyà 10:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Jèhófà, fi ìdájọ́ tọ́ mi sọ́nà,Àmọ́ kì í ṣe nínú ìbínú rẹ,+ kí o má bàa pa mí run.+
4 Ọba alágbára ńlá tó nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo ni.+ O ti fìdí ohun tí ó tọ́ múlẹ̀ ṣinṣin. O ti mú kí ìdájọ́ òdodo+ àti òtítọ́ wà ní Jékọ́bù.