Ìdárò 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Wọ́n ń béèrè lọ́wọ́ àwọn ìyá wọn pé: “Ọkà àti wáìnì dà?”+ Bí wọ́n ti ń kú lọ bí ẹni tó fara gbọgbẹ́ ní àwọn gbàgede ìlú,Tí ẹ̀mí* wọn sì ń kú lọ lọ́wọ́ ìyá wọn. Sefanáyà 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n á kó ọrọ̀ wọn lọ, wọ́n á sì pa ilé wọn run.+ Wọ́n á kọ́ ilé, ṣùgbọ́n wọn kò ní gbé inú rẹ̀;Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, ṣùgbọ́n wọn kò ní mu wáìnì rẹ̀.+
12 Wọ́n ń béèrè lọ́wọ́ àwọn ìyá wọn pé: “Ọkà àti wáìnì dà?”+ Bí wọ́n ti ń kú lọ bí ẹni tó fara gbọgbẹ́ ní àwọn gbàgede ìlú,Tí ẹ̀mí* wọn sì ń kú lọ lọ́wọ́ ìyá wọn.
13 Wọ́n á kó ọrọ̀ wọn lọ, wọ́n á sì pa ilé wọn run.+ Wọ́n á kọ́ ilé, ṣùgbọ́n wọn kò ní gbé inú rẹ̀;Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, ṣùgbọ́n wọn kò ní mu wáìnì rẹ̀.+