-
Diutarónómì 28:51Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
51 Wọ́n á jẹ àwọn ọmọ ẹran ọ̀sìn rẹ àti èso ilẹ̀ rẹ títí wọ́n fi máa pa ọ́ run. Wọn ò ní ṣẹ́ ọkà kankan kù fún ọ àti wáìnì tàbí òróró tuntun, ọmọ màlúù tàbí àgùntàn, títí wọ́n fi máa pa ọ́ run.+
-
-
Àìsáyà 3:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Wò ó! Olúwa tòótọ́, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,
Ó ń mú gbogbo ìtìlẹ́yìn àtàwọn ohun tí wọ́n nílò ní Jerúsálẹ́mù àti Júdà kúrò,
Gbogbo ìtìlẹ́yìn oúnjẹ àti omi,+
-