-
Ẹ́kísódù 20:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Gbogbo àwọn èèyàn náà ń rí ààrá tó ń sán àti mànàmáná tó ń kọ yẹ̀rì, wọ́n ń gbọ́ ìró ìwo, wọ́n sì ń rí òkè tó ń yọ èéfín; àwọn ohun tí wọ́n rí yìí bà wọ́n lẹ́rù, wọ́n sì ń gbọ̀n, wọ́n wá dúró ní òkèèrè.+
-