-
Àìsáyà 30:23, 24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ó máa rọ òjò sí ohun tí o gbìn sínú ilẹ̀,+ oúnjẹ tí ilẹ̀ bá sì mú jáde máa pọ̀ rẹpẹtẹ, ó sì máa lọ́ràá.*+ Ní ọjọ́ yẹn, ẹran ọ̀sìn rẹ máa jẹko ní àwọn pápá tó fẹ̀.+ 24 Àwọn màlúù àti àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tó ń ṣiṣẹ́ lórí ilẹ̀ máa jẹ oúnjẹ ẹran tí wọ́n fi ewéko olómi-kíkan sí, èyí tí wọ́n fi ṣọ́bìrì àti àmúga fẹ́.
-