Ìfihàn 6:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lẹ́yìn náà, àwọn ọba ayé, àwọn aláṣẹ, àwọn ọ̀gágun, àwọn ọlọ́rọ̀, àwọn alágbára, gbogbo ẹrú àti gbogbo àwọn tó wà lómìnira fi ara wọn pa mọ́ sínú àwọn ihò àti sáàárín àwọn àpáta àwọn òkè.+
15 Lẹ́yìn náà, àwọn ọba ayé, àwọn aláṣẹ, àwọn ọ̀gágun, àwọn ọlọ́rọ̀, àwọn alágbára, gbogbo ẹrú àti gbogbo àwọn tó wà lómìnira fi ara wọn pa mọ́ sínú àwọn ihò àti sáàárín àwọn àpáta àwọn òkè.+