Àìsáyà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ inú àpáta, kí o sì fi ara rẹ pa mọ́ sínú iyẹ̀pẹ̀,Torí bí Jèhófà ṣe wà níbí ń dẹ́rù bani,Iyì rẹ̀ sì ga lọ́lá.+ Àìsáyà 2:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àwọn èèyàn sì máa wọ ihò inú àpátaÀti àwọn ihò inú ilẹ̀,+Torí bí Jèhófà ṣe wà níbí ń dẹ́rù bani,Iyì rẹ̀ sì ga lọ́lá,+Nígbà tó dìde láti mi ayé jìgìjìgì, kó sì kó jìnnìjìnnì bá a.
10 Wọ inú àpáta, kí o sì fi ara rẹ pa mọ́ sínú iyẹ̀pẹ̀,Torí bí Jèhófà ṣe wà níbí ń dẹ́rù bani,Iyì rẹ̀ sì ga lọ́lá.+
19 Àwọn èèyàn sì máa wọ ihò inú àpátaÀti àwọn ihò inú ilẹ̀,+Torí bí Jèhófà ṣe wà níbí ń dẹ́rù bani,Iyì rẹ̀ sì ga lọ́lá,+Nígbà tó dìde láti mi ayé jìgìjìgì, kó sì kó jìnnìjìnnì bá a.