Àìsáyà 65:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ṣárónì+ máa di ibi tí àgùntàn á ti máa jẹko,Àfonífojì* Ákórì+ sì máa di ibi ìsinmi àwọn màlúùFún àwọn èèyàn mi tó ń wá mi.
10 Ṣárónì+ máa di ibi tí àgùntàn á ti máa jẹko,Àfonífojì* Ákórì+ sì máa di ibi ìsinmi àwọn màlúùFún àwọn èèyàn mi tó ń wá mi.