2 Kíróníkà 32:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ní àkókò náà, Hẹsikáyà ṣàìsàn dé ojú ikú, ó sì gbàdúrà sí Jèhófà.+ Ọlọ́run dá a lóhùn, ó sì fún un ní àmì kan.*+
24 Ní àkókò náà, Hẹsikáyà ṣàìsàn dé ojú ikú, ó sì gbàdúrà sí Jèhófà.+ Ọlọ́run dá a lóhùn, ó sì fún un ní àmì kan.*+