ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 20:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 “Pa dà lọ sọ fún Hẹsikáyà aṣáájú àwọn èèyàn mi pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Dáfídì baba ńlá rẹ sọ nìyí: “Mo ti gbọ́ àdúrà rẹ. Mo ti rí omijé rẹ.+ Wò ó, màá mú ọ lára dá.+ Ní ọ̀túnla, wàá lọ sí ilé Jèhófà.+

  • Sáàmù 84:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Àárò ń sọ mí,*

      Àní, àárẹ̀ ti mú mi bó ṣe ń wù mí

      Láti wá sí àwọn àgbàlá Jèhófà.+

      Gbogbo ọkàn àti gbogbo ara mi ni mo fi ń kígbe ayọ̀ sí Ọlọ́run alààyè.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́