Sáàmù 42:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Bí ọkàn àgbọ̀nrín ṣe máa ń fà sí odò,Bẹ́ẹ̀ ni ọkàn mi ṣe ń fà sí ọ, ìwọ Ọlọ́run mi. 2 Mò* ń wá Ọlọ́run, Ọlọ́run alààyè, bí ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ ṣe ń wá omi.+ Ìgbà wo ni kí n wá, kí n sì fara hàn níwájú Ọlọ́run?+ Sáàmù 63:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 63 Ọlọ́run, ìwọ ni Ọlọ́run mi, mò ń wá ọ.+ Ọkàn mi ń fà sí ọ.*+ Àárẹ̀ ti mú mi* nítorí bó ṣe ń wù mí láti rí ọNí ilẹ̀ tó gbẹ táútáú, níbi tí kò sí omi.+ 2 Torí náà, mo wò ọ́ ní ibi mímọ́;Mo rí agbára rẹ àti ògo rẹ.+
42 Bí ọkàn àgbọ̀nrín ṣe máa ń fà sí odò,Bẹ́ẹ̀ ni ọkàn mi ṣe ń fà sí ọ, ìwọ Ọlọ́run mi. 2 Mò* ń wá Ọlọ́run, Ọlọ́run alààyè, bí ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ ṣe ń wá omi.+ Ìgbà wo ni kí n wá, kí n sì fara hàn níwájú Ọlọ́run?+
63 Ọlọ́run, ìwọ ni Ọlọ́run mi, mò ń wá ọ.+ Ọkàn mi ń fà sí ọ.*+ Àárẹ̀ ti mú mi* nítorí bó ṣe ń wù mí láti rí ọNí ilẹ̀ tó gbẹ táútáú, níbi tí kò sí omi.+ 2 Torí náà, mo wò ọ́ ní ibi mímọ́;Mo rí agbára rẹ àti ògo rẹ.+