Sáàmù 63:àkọlé Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Orin Dáfídì, nígbà tó wà ní aginjù Júdà.+ Sáàmù 143:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mo tẹ́ ọwọ́ mi sí ọ;Mò* ń wá ọ bí ilẹ̀ tó gbẹ táútáú ṣe ń wá òjò.+ (Sélà)