Sáàmù 63:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 63 Ọlọ́run, ìwọ ni Ọlọ́run mi, mò ń wá ọ.+ Ọkàn mi ń fà sí ọ.*+ Àárẹ̀ ti mú mi* nítorí bó ṣe ń wù mí láti rí ọNí ilẹ̀ tó gbẹ táútáú, níbi tí kò sí omi.+
63 Ọlọ́run, ìwọ ni Ọlọ́run mi, mò ń wá ọ.+ Ọkàn mi ń fà sí ọ.*+ Àárẹ̀ ti mú mi* nítorí bó ṣe ń wù mí láti rí ọNí ilẹ̀ tó gbẹ táútáú, níbi tí kò sí omi.+