Àìsáyà 24:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi máa yin Jèhófà lógo ní agbègbè ìmọ́lẹ̀;*+Ní àwọn erékùṣù òkun, wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà, Ọlọ́run Ísírẹ́lì lógo.+
15 Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi máa yin Jèhófà lógo ní agbègbè ìmọ́lẹ̀;*+Ní àwọn erékùṣù òkun, wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà, Ọlọ́run Ísírẹ́lì lógo.+