Àìsáyà 11:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà tún máa na ọwọ́ rẹ̀ lẹ́ẹ̀kejì, láti gba àṣẹ́kù àwọn èèyàn rẹ̀ pa dà, àwọn tó ṣẹ́ kù láti Ásíríà,+ Íjíbítì,+ Pátírọ́sì,+ Kúṣì,+ Élámù,+ Ṣínárì,* Hámátì àti àwọn erékùṣù òkun.+ Àìsáyà 60:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí àwọn erékùṣù máa gbẹ́kẹ̀ lé mi,+Àwọn ọkọ̀ òkun Táṣíṣì ló ṣíwájú,*Láti kó àwọn ọmọ rẹ wá láti ọ̀nà jíjìn,+Pẹ̀lú fàdákà wọn àti wúrà wọn,Síbi orúkọ Jèhófà Ọlọ́run rẹ àti sọ́dọ̀ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Torí ó máa ṣe ọ́ lógo.*+
11 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà tún máa na ọwọ́ rẹ̀ lẹ́ẹ̀kejì, láti gba àṣẹ́kù àwọn èèyàn rẹ̀ pa dà, àwọn tó ṣẹ́ kù láti Ásíríà,+ Íjíbítì,+ Pátírọ́sì,+ Kúṣì,+ Élámù,+ Ṣínárì,* Hámátì àti àwọn erékùṣù òkun.+
9 Torí àwọn erékùṣù máa gbẹ́kẹ̀ lé mi,+Àwọn ọkọ̀ òkun Táṣíṣì ló ṣíwájú,*Láti kó àwọn ọmọ rẹ wá láti ọ̀nà jíjìn,+Pẹ̀lú fàdákà wọn àti wúrà wọn,Síbi orúkọ Jèhófà Ọlọ́run rẹ àti sọ́dọ̀ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Torí ó máa ṣe ọ́ lógo.*+