Sekaráyà 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Torí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘“Èmi yóò pa dà ṣàánú Jerúsálẹ́mù,”+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, “wọn yóò kọ́ ilé mi sí ibẹ̀,+ wọn yóò sì na okùn ìdíwọ̀n sórí Jerúsálẹ́mù.”’+
16 “Torí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘“Èmi yóò pa dà ṣàánú Jerúsálẹ́mù,”+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, “wọn yóò kọ́ ilé mi sí ibẹ̀,+ wọn yóò sì na okùn ìdíwọ̀n sórí Jerúsálẹ́mù.”’+